Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Adájọ́ 7:4 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA tún wí fún Gideoni pé, “Àwọn tí wọ́n ṣẹ́kù yìí pọ̀jù sibẹsibẹ. Kó wọn lọ sí etí odò, n óo sì bá ọ dán wọn wò níbẹ̀. Ẹnikẹ́ni tí mo bá wí fún ọ pé yóo lọ, òun ni yóo lọ, ẹnikẹ́ni tí mo bá sì wí fún ọ pé kò ní lọ, kò gbọdọ̀ lọ.”

Ka pipe ipin Àwọn Adájọ́ 7

Wo Àwọn Adájọ́ 7:4 ni o tọ