Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Adájọ́ 7:18 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí èmi ati àwọn tí wọ́n wà lọ́dọ̀ mi bá fọn fèrè, ẹ̀yin náà ẹ fọn fèrè tiyín ní gbogbo àyíká àgọ́ náà, ẹ óo sì pariwo pé, ‘Fún OLUWA, ati fún Gideoni.’ ”

Ka pipe ipin Àwọn Adájọ́ 7

Wo Àwọn Adájọ́ 7:18 ni o tọ