Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Adájọ́ 7:15 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí Gideoni gbọ́ bí ó ti rọ́ àlá yìí, ati ìtumọ̀ rẹ̀, ó yin OLUWA. Ó pada sí ibùdó Israẹli, ó ní, “Ẹ dìde, nítorí OLUWA ti fi àwọn ọmọ ogun Midiani le yín lọ́wọ́.”

Ka pipe ipin Àwọn Adájọ́ 7

Wo Àwọn Adájọ́ 7:15 ni o tọ