Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Adájọ́ 7:13 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí Gideoni dé ibẹ̀, ó gbọ́ tí ẹnìkan ń rọ́ àlá tí ó lá fún ẹlẹgbẹ́ rẹ̀ kan pé, “Mo lá àlá kan, mo rí i tí àkàrà ọkà baali kan ré bọ́ sinu ibùdó àwọn ará Midiani. Bí ó ti bọ́ lu àgọ́ náà, ó wó o lulẹ̀, ó sì dojú rẹ̀ délẹ̀, àgọ́ náà sì tẹ́ sílẹ̀ pẹrẹsẹ.”

Ka pipe ipin Àwọn Adájọ́ 7

Wo Àwọn Adájọ́ 7:13 ni o tọ