Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Adájọ́ 6:39 BIBELI MIMỌ (BM)

Gideoni tún wí fún Ọlọrun pé, “Jọ̀wọ́, má jẹ́ kí inú bí ọ sí mi, ẹ̀ẹ̀kan ṣoṣo yìí ni ó kù tí mo fẹ́ sọ̀rọ̀; jọ̀wọ́ jẹ́ kí n tún dán kinní kan wò pẹlu irun aguntan yìí lẹ́ẹ̀kan sí i, jẹ́ kí gbogbo irun yìí gbẹ ṣugbọn kí ìrì sẹ̀ sí gbogbo ilẹ̀, kí ó sì tutù.”

Ka pipe ipin Àwọn Adájọ́ 6

Wo Àwọn Adájọ́ 6:39 ni o tọ