Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Adájọ́ 6:33 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà náà ni gbogbo àwọn ará ilẹ̀ Midiani ati àwọn ará ilẹ̀ Amaleki ati àwọn ará ilẹ̀ tí ó wà ní ìhà ìlà oòrùn kó ara wọn jọ, wọ́n la odò Jọdani kọjá, wọ́n sì pàgọ́ wọn sí àfonífojì Jesireeli.

Ka pipe ipin Àwọn Adájọ́ 6

Wo Àwọn Adájọ́ 6:33 ni o tọ