Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Adájọ́ 6:14 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn OLUWA yipada sí i, ó sì dá a lóhùn pé, “Lọ pẹlu agbára rẹ yìí, kí o sì gba Israẹli kúrò lọ́wọ́ àwọn ará Midiani, ṣebí èmi ni mo rán ọ.”

Ka pipe ipin Àwọn Adájọ́ 6

Wo Àwọn Adájọ́ 6:14 ni o tọ