Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Adájọ́ 5:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Ní gbogbo ìgbà tí àwọn ọmọ Israẹli dá oriṣa titun,ogun bo gbogbo ẹnubodè.Ninu bí ọ̀kẹ́ meji (40,000) ọkunrin tí wọ́n wà ní Israẹli,ǹjẹ́ a rí ẹnikẹ́ni tí ó ní apata tabi ọ̀kọ̀?

Ka pipe ipin Àwọn Adájọ́ 5

Wo Àwọn Adájọ́ 5:8 ni o tọ