Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Adájọ́ 5:28 BIBELI MIMỌ (BM)

Ìyá Sisera ń yọjú láti ojú fèrèsé,ó bẹ̀rẹ̀ sí wo ọ̀nà láti ibi ihò fèrèsé.Ó ní, “Kí ló dé tí àwọn kẹ̀kẹ́ ogun rẹ̀ fi pẹ́ tóbẹ́ẹ̀ kí wọ́n tó dé?Kí ló dé tí ó fi pẹ́ tóbẹ́ẹ̀ kí á tó gbúròó ẹsẹ̀ àwọn ẹṣintí wọ́n ń wọ́ kẹ̀kẹ́ ogun rẹ̀?”

Ka pipe ipin Àwọn Adájọ́ 5

Wo Àwọn Adájọ́ 5:28 ni o tọ