Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Adájọ́ 4:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó ranṣẹ pe Baraki, ọmọ Abinoamu, ní Kedeṣi, tí ó wà ní Nafutali, ó wí fún un pé, “OLUWA Ọlọrun Israẹli ń pàṣẹ fún ọ pé kí o lọ kó àwọn eniyan rẹ̀ jọ ní òkè Tabori. Kó ẹgbaarun (10,000) eniyan ninu ẹ̀yà Nafutali ati Sebuluni jọ.

Ka pipe ipin Àwọn Adájọ́ 4

Wo Àwọn Adájọ́ 4:6 ni o tọ