Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Adájọ́ 3:13 BIBELI MIMỌ (BM)

Egiloni yìí kó àwọn ará Amoni ati àwọn ará Amaleki sòdí, wọ́n lọ ṣẹgun àwọn ọmọ Israẹli, wọ́n sì gba Jẹriko, ìlú ọlọ́pẹ, lọ́wọ́ wọn.

Ka pipe ipin Àwọn Adájọ́ 3

Wo Àwọn Adájọ́ 3:13 ni o tọ