Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Adájọ́ 21:24-25 BIBELI MIMỌ (BM)

24. Àwọn ọmọ Israẹli bá kúrò níbẹ̀, gbogbo wọ́n sì pada sí ilẹ̀ wọn, olukuluku pada lọ sí ìlú rẹ̀, sí ààrin ẹbí rẹ̀.

25. Kò sí ọba ní ilẹ̀ Israẹli ní gbogbo àkókò náà, olukuluku bá bẹ̀rẹ̀ sí ṣe bí ó ti tọ́ ní ojú ara rẹ̀.

Ka pipe ipin Àwọn Adájọ́ 21