Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Adájọ́ 21:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Ìjọ eniyan náà bá rán ẹgbaafa (12,000) ninu àwọn jagunjagun wọn tí wọ́n gbójú jùlọ, wọ́n sì fún wọn láṣẹ pé, “Ẹ lọ fi idà pa gbogbo àwọn tí ń gbé Jabeṣi Gileadi ati obinrin wọn, ati àwọn ọmọ wẹ́wẹ́ wọn.

Ka pipe ipin Àwọn Adájọ́ 21

Wo Àwọn Adájọ́ 21:10 ni o tọ