Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Adájọ́ 20:45 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n bá yipada, wọ́n sá gba ọ̀nà aṣálẹ̀ tí ó lọ sí ibi àpáta Rimoni, àwọn ọmọ Israẹli sì tún pa ẹẹdẹgbaata (5,000) ninu wọn ní ojú ọ̀nà. Wọ́n ń lé wọn lọ tete títí dé Gidomu, wọ́n sì tún pa ẹgbaa (2,000) eniyan ninu wọn.

Ka pipe ipin Àwọn Adájọ́ 20

Wo Àwọn Adájọ́ 20:45 ni o tọ