Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Adájọ́ 20:40 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn nígbà tí èéfín tí àwọn ọmọ ogun Israẹli fi ṣe àmì bẹ̀rẹ̀ sí yọ sókè láàrin ìlú, àwọn ará Bẹnjamini wo ẹ̀yìn, wọ́n rí i pé èéfín ti sọ, ó sì ti gba ìlú kan.

Ka pipe ipin Àwọn Adájọ́ 20

Wo Àwọn Adájọ́ 20:40 ni o tọ