Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Adájọ́ 20:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọmọ Lefi, ọkọ obinrin tí wọ́n pa, bá dáhùn pé, “Èmi ati obinrin mi ni a yà sí Gibea ní ilẹ̀ àwọn ará Bẹnjamini pé kí á sùn níbẹ̀.

Ka pipe ipin Àwọn Adájọ́ 20

Wo Àwọn Adájọ́ 20:4 ni o tọ