Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Adájọ́ 20:33 BIBELI MIMỌ (BM)

Olukuluku àwọn ọmọ Israẹli bá kúrò ní ààyè rẹ̀, wọ́n lọ tò ní Baalitamari. Àwọn ọmọ Israẹli tí wọ́n ba ní ibùba bá jáde kúrò níbi tí wọ́n ba sí ní apá ìwọ̀ oòrùn Geba.

Ka pipe ipin Àwọn Adájọ́ 20

Wo Àwọn Adájọ́ 20:33 ni o tọ