Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Adájọ́ 20:28 BIBELI MIMỌ (BM)

Finehasi ọmọ Eleasari, ọmọ Aaroni ló ń ṣe iṣẹ́ alufaa ní àkókò náà, àwọn ọmọ Israẹli tún bèèrè pé, “Ṣé kí á tún lọ gbógun ti àwọn ará Bẹnjamini tíí ṣe arakunrin wa àbí kí á dáwọ́ dúró?”OLUWA dá wọn lóhùn, ó ní, “Ẹ lọ gbógun tì wọ́n, nítorí pé, lọ́la ni n óo fi wọ́n le yín lọ́wọ́.”

Ka pipe ipin Àwọn Adájọ́ 20

Wo Àwọn Adájọ́ 20:28 ni o tọ