Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Adájọ́ 20:26 BIBELI MIMỌ (BM)

Gbogbo àwọn ọmọ ogun Israẹli bá lọ sí Bẹtẹli, wọ́n jókòó wọ́n sọkún níbẹ̀ níwájú OLUWA, wọ́n gbààwẹ̀ títí di ìrọ̀lẹ́; wọ́n sì rú ẹbọ sísun ati ẹbọ alaafia níwájú OLUWA.

Ka pipe ipin Àwọn Adájọ́ 20

Wo Àwọn Adájọ́ 20:26 ni o tọ