Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Adájọ́ 20:23 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n bá lọ sọkún níwájú OLUWA títí di ìrọ̀lẹ́, wọ́n wádìí lọ́dọ̀ OLUWA, wọ́n ní, “Ṣé kí á tún gbógun ti àwọn ará Bẹnjamini tí í ṣe àwọn arakunrin wa?”OLUWA dá wọn lóhùn pé kí wọ́n lọ gbógun tì wọ́n.

Ka pipe ipin Àwọn Adájọ́ 20

Wo Àwọn Adájọ́ 20:23 ni o tọ