Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Adájọ́ 20:18 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn ọmọ Israẹli gbéra lọ sí Bẹtẹli, wọ́n lọ wádìí lọ́dọ̀ Ọlọrun; ẹ̀yà tí yóo kọ́kọ́ gbógun ti ẹ̀yà Bẹnjamini.OLUWA dá wọn lóhùn pé ẹ̀yà Juda ni yóo kọ́kọ́ gbógun tì wọ́n.

Ka pipe ipin Àwọn Adájọ́ 20

Wo Àwọn Adájọ́ 20:18 ni o tọ