Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Adájọ́ 20:16 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹẹdẹgbẹrin (700) akọni ọkunrin tí wọn ń lo ọwọ́ òsì wà láàrin àwọn ọmọ ogun wọnyi. Wọ́n mọ kànnàkànnà ta, tóbẹ́ẹ̀ tí ó jẹ́ pé wọ́n lè ta á mọ́ fọ́nrán òwú láì tàsé.

Ka pipe ipin Àwọn Adájọ́ 20

Wo Àwọn Adájọ́ 20:16 ni o tọ