Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Adájọ́ 20:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Ìdámẹ́wàá àwọn ọkunrin tí wọ́n wà ní Israẹli yóo máa pèsè oúnjẹ fún àwọn ọmọ ogun, àwọn yòókù yóo lọ jẹ àwọn ará Gibea níyà fún ìwà burúkú tí wọ́n hù ní Israẹli yìí.”

Ka pipe ipin Àwọn Adájọ́ 20

Wo Àwọn Adájọ́ 20:10 ni o tọ