Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Adájọ́ 2:19 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn bí aṣiwaju yìí bá ti kú, kíá, wọn a tún ti yipada, wọn a sì tún ti máa ṣe ohun tí ó burú ju ohun tí àwọn baba wọn ti ṣe lọ. Wọn a máa lọ sọ́dọ̀ àwọn oriṣa, wọ́n a máa bọ wọ́n, wọn a sì máa foríbalẹ̀ fún wọn. Wọn kì í sì í fi ìṣe wọn ati oríkunkun wọn sílẹ̀.

Ka pipe ipin Àwọn Adájọ́ 2

Wo Àwọn Adájọ́ 2:19 ni o tọ