Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Adájọ́ 2:15 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbàkúùgbà tí wọ́n bá jáde lọ láti jagun, OLUWA á kẹ̀yìn sí wọn gẹ́gẹ́ bí ó ti kìlọ̀ fún wọn tí ó sì búra fún wọn, ìdààmú a sì dé bá wọn.

Ka pipe ipin Àwọn Adájọ́ 2

Wo Àwọn Adájọ́ 2:15 ni o tọ