Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Adájọ́ 19:26 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí ilẹ̀ mọ́, obinrin yìí bá lọ wó lulẹ̀ sì ẹnu ọ̀nà baba arúgbó náà níbi tí ọkunrin tí ó mú un wá wà, ó wà níbẹ̀ títí tí ilẹ̀ fi mọ́ kedere.

Ka pipe ipin Àwọn Adájọ́ 19

Wo Àwọn Adájọ́ 19:26 ni o tọ