Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Adájọ́ 19:24 BIBELI MIMỌ (BM)

Mo ní ọmọbinrin kan tí ó jẹ́ wundia, ọkunrin náà sì ní obinrin kan, ẹ jẹ́ kí n mú wọn jáde sí yín nisinsinyii, kí ẹ sì ṣe wọ́n bí ẹ bá ti fẹ́, kí ẹ tẹ́ ìfẹ́ yín lọ́rùn lára wọn, ṣugbọn ẹ má ṣe hu irú ìwà burúkú yìí sí ọkunrin náà.”

Ka pipe ipin Àwọn Adájọ́ 19

Wo Àwọn Adájọ́ 19:24 ni o tọ