Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Adájọ́ 19:11 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí wọ́n súnmọ́ Jebusi, ilẹ̀ ti ń ṣú lọ, iranṣẹ rẹ̀ sọ fún un pé, “Jẹ́ kí á dúró ní ìlú àwọn ará Jebusi yìí kí á sì sùn níbẹ̀ lónìí.”

Ka pipe ipin Àwọn Adájọ́ 19

Wo Àwọn Adájọ́ 19:11 ni o tọ