Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Adájọ́ 18:30 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn ará Dani gbé ère dídà náà kalẹ̀ fún ara wọn. Jonatani ọmọ Geriṣomu, ọmọ Mose ati àwọn ọmọ rẹ̀ ni wọ́n jẹ́ alufaa fún àwọn ẹ̀yà Dani títí di àkókò tí wọ́n kó gbogbo agbègbè wọn ní ìgbèkùn.

Ka pipe ipin Àwọn Adájọ́ 18

Wo Àwọn Adájọ́ 18:30 ni o tọ