Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Adájọ́ 18:27 BIBELI MIMỌ (BM)

Lẹ́yìn tí àwọn ará Dani ti kó oriṣa Mika, tí wọ́n sì ti gba alufaa rẹ̀, wọ́n lọ sí Laiṣi, wọ́n gbógun ti àwọn eniyan náà níbi tí wọ́n jókòó sí jẹ́jẹ́ láì bẹ̀rù; wọ́n pa wọ́n, wọ́n sì dáná sun ìlú wọn.

Ka pipe ipin Àwọn Adájọ́ 18

Wo Àwọn Adájọ́ 18:27 ni o tọ