Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Adájọ́ 17:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Mika ní ojúbọ kan fún ara rẹ̀, ó dá ẹ̀wù funfun kan, ó sì ṣe àwọn ère kéékèèké. Ó fi ọ̀kan ninu àwọn ọmọ rẹ̀ ṣe alufaa oriṣa rẹ̀.

Ka pipe ipin Àwọn Adájọ́ 17

Wo Àwọn Adájọ́ 17:5 ni o tọ