Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Adájọ́ 16:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn ọba Filistia wá sọ́dọ̀ obinrin yìí, wọ́n ní, “Tan ọkọ rẹ, kí o sì mọ àṣírí agbára rẹ̀, ati ọ̀nà tí a fi lè kápá rẹ̀; kí á lè dì í lókùn kí á sì ṣẹgun rẹ̀. Ẹnìkọ̀ọ̀kan wa yóo sì fún ọ ní ẹẹdẹgbẹfa (1,100) owó fadaka.”

Ka pipe ipin Àwọn Adájọ́ 16

Wo Àwọn Adájọ́ 16:5 ni o tọ