Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Adájọ́ 16:31 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn arakunrin rẹ̀, ati gbogbo àwọn ará ilé rẹ̀ bá wá gbé òkú rẹ̀, wọ́n lọ sin ín sáàrin Sora ati Eṣitaolu ninu ibojì Manoa, baba rẹ̀. Ogún ọdún ni ó fi ṣe aṣiwaju ní Israẹli.

Ka pipe ipin Àwọn Adájọ́ 16

Wo Àwọn Adájọ́ 16:31 ni o tọ