Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Adájọ́ 16:24 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí àwọn eniyan rí i, wọ́n yin oriṣa wọn; wọ́n ní, “Oriṣa wa ti fi ọ̀tá wa lé wa lọ́wọ́, ẹni tí ó sọ ilẹ̀ wa di ahoro tí ó sì pa ọpọlọpọ ninu wa.”

Ka pipe ipin Àwọn Adájọ́ 16

Wo Àwọn Adájọ́ 16:24 ni o tọ