Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Adájọ́ 16:15 BIBELI MIMỌ (BM)

Delila tún sọ fún un pé, “Báwo ni o ṣe lè wí pé o nífẹ̀ẹ́ mí, nígbà tí ọkàn rẹ kò sí lọ́dọ̀ mi. O ti fi mí ṣe ẹlẹ́yà nígbà mẹta, o kò sì sọ àṣírí agbára ńlá rẹ fún mi.”

Ka pipe ipin Àwọn Adájọ́ 16

Wo Àwọn Adájọ́ 16:15 ni o tọ