Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Adájọ́ 16:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Delila tún wí fún Samsoni pé, “Ò ń fi mí ṣe ẹlẹ́yà, o sì ń purọ́ fún mi. Jọ̀wọ́ sọ bí eniyan ṣe le dè ọ́ lókùn fún mi.”

Ka pipe ipin Àwọn Adájọ́ 16

Wo Àwọn Adájọ́ 16:10 ni o tọ