Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Adájọ́ 15:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Baba iyawo rẹ̀ wí fún un pé, “Mo rò pé lóòótọ́ ni o kórìíra iyawo rẹ, nítorí náà, mo ti fi fún ẹni tí ó jẹ́ ọrẹ rẹ tímọ́tímọ́, ninu àwọn ẹlẹgbẹ́ rẹ. Ṣé ìwọ náà rí i pé àbúrò rẹ̀ lẹ́wà jù ú lọ, jọ̀wọ́ fẹ́ ẹ dípò rẹ̀.”

Ka pipe ipin Àwọn Adájọ́ 15

Wo Àwọn Adájọ́ 15:2 ni o tọ