Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Adájọ́ 14:13 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn bí ẹ kò bá lè túmọ̀ àlọ́ náà, ẹnìkọ̀ọ̀kan yín yóo fún mi ní ẹ̀wù funfun kọ̀ọ̀kan ati aṣọ àríyá kọ̀ọ̀kan.”Wọ́n bá dáhùn pé, “Pa àlọ́ rẹ kí á gbọ́.”

Ka pipe ipin Àwọn Adájọ́ 14

Wo Àwọn Adájọ́ 14:13 ni o tọ