Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Adájọ́ 13:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí pé, o óo lóyún, o óo sì bí ọmọkunrin kan. Abẹ kò gbọdọ̀ kan orí rẹ̀, nítorí pé, Nasiri Ọlọrun ni yóo jẹ́ láti ọjọ́ ìbí rẹ̀; òun ni yóo sì gba Israẹli sílẹ̀ lọ́wọ́ àwọn ará Filistia.”

Ka pipe ipin Àwọn Adájọ́ 13

Wo Àwọn Adájọ́ 13:5 ni o tọ