Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Adájọ́ 13:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí ó di ọjọ́ kan, angẹli OLUWA fi ara han iyawo Manoa yìí, ó wí fún un pé, “Lóòótọ́, àgàn ni ọ́, ṣugbọn o óo lóyún, o óo sì bí ọmọkunrin kan.

Ka pipe ipin Àwọn Adájọ́ 13

Wo Àwọn Adájọ́ 13:3 ni o tọ