Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Adájọ́ 13:16 BIBELI MIMỌ (BM)

Angẹli OLUWA náà dá Manoa lóhùn, ó ní, “Bí o bá dá mi dúró, n kò ní jẹ ninu oúnjẹ rẹ, ṣugbọn tí o bá fẹ́ tọ́jú ohun tí o fẹ́ fi rú ẹbọ sísun, OLUWA ni kí o rú u sí.” Manoa kò mọ̀ pé angẹli OLUWA ni.

Ka pipe ipin Àwọn Adájọ́ 13

Wo Àwọn Adájọ́ 13:16 ni o tọ