Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Adájọ́ 13:12 BIBELI MIMỌ (BM)

Manoa tún bèèrè pé, “Nígbà tí ọ̀rọ̀ rẹ bá ṣẹ, báwo ni ìgbé ayé ọmọ náà yóo rí? Irú kí ni yóo sì máa ṣe?”

Ka pipe ipin Àwọn Adájọ́ 13

Wo Àwọn Adájọ́ 13:12 ni o tọ