Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Adájọ́ 11:33 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó bẹ̀rẹ̀ sí pa wọ́n láti Aroeri títí dé agbègbè Miniti tí ó fi wọ Abeli Keramimu. Àwọn ìlú tí ó run jẹ́ ogún. Àwọn ọmọ Israẹli sì ṣẹgun àwọn ará Amoni.

Ka pipe ipin Àwọn Adájọ́ 11

Wo Àwọn Adájọ́ 11:33 ni o tọ