Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Adájọ́ 11:28 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn ọba àwọn ará Amoni kò tilẹ̀ fetí sí iṣẹ́ tí Jẹfuta rán sí i rárá.

Ka pipe ipin Àwọn Adájọ́ 11

Wo Àwọn Adájọ́ 11:28 ni o tọ