Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Adájọ́ 11:24 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣé ohun tí Kemoṣi, oriṣa rẹ fún ọ, kò tó ọ ni? Gbogbo ohun tí OLUWA Ọlọrun wa ti gbà fún wa ni a óo fọwọ́ mú.

Ka pipe ipin Àwọn Adájọ́ 11

Wo Àwọn Adájọ́ 11:24 ni o tọ