Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Adájọ́ 11:21 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA Ọlọrun Israẹli bà fi Sihoni ati gbogbo àwọn eniyan rẹ̀ lé Israẹli lọ́wọ́, Israẹli ṣẹgun wọn, wọ́n sì gba ilẹ̀ àwọn ará Amori tí wọ́n ń gbé agbègbè náà.

Ka pipe ipin Àwọn Adájọ́ 11

Wo Àwọn Adájọ́ 11:21 ni o tọ