Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Adájọ́ 11:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn iyawo Gileadi gan-an bí àwọn ọmọkunrin mìíràn. Nígbà tí àwọn ọmọkunrin wọnyi dàgbà, wọ́n lé Jẹfuta jáde, wọ́n sọ fún un pé, “O kò lè bá wa pín ninu ogún baba wa, nítorí ọmọ obinrin mìíràn ni ọ́.”

Ka pipe ipin Àwọn Adájọ́ 11

Wo Àwọn Adájọ́ 11:2 ni o tọ