Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Adájọ́ 10:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn ará Amoni sì tún kọjá sí òdìkejì odò Jọdani, wọ́n bá àwọn ẹ̀yà Juda, ẹ̀yà Bẹnjamini ati ẹ̀yà Manase jà, gbogbo Israẹli patapata ni wọ́n ń pọ́n lójú.

Ka pipe ipin Àwọn Adájọ́ 10

Wo Àwọn Adájọ́ 10:9 ni o tọ