Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Adájọ́ 10:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó bí ọgbọ̀n ọmọkunrin, tí wọ́n ń gun ọgbọ̀n kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́, ọgbọ̀n ìlú ni wọ́n sì tẹ̀dó, tí wọn ń pe orúkọ wọn ní Hafoti Jairi títí di òní olónìí. Wọ́n wà ní ilẹ̀ Gileadi.

Ka pipe ipin Àwọn Adájọ́ 10

Wo Àwọn Adájọ́ 10:4 ni o tọ