Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Adájọ́ 1:25 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọkunrin náà bá fi ọ̀nà tí wọn ń gbà wọ ìlú náà hàn wọ́n, wọ́n bá fi idà pa gbogbo àwọn ará ìlú náà, ṣugbọn wọ́n jẹ́ kí ọkunrin náà ati gbogbo ìdílé rẹ̀ jáde lọ.

Ka pipe ipin Àwọn Adájọ́ 1

Wo Àwọn Adájọ́ 1:25 ni o tọ